Arí Ire – Tofúnmi Adébáyọ̀ Ayọ̀délé

We Found Favour

683
DOWNLOAD NOW

B’odun esi see le to
Ama tun wa laye
B’esu see gb’ogun to
Ama ri aanu gba
Loju amoko bii ki’le od’amo
Ari ire gba ao pare m’aye
Ari ire gba ao pare m’aye

Away la win
Olorun Loni glory
Ota gb’ogun titi
Lotun losi Lona wa gbogbo
Ninu isoro wa awo Jesu oju oti wa,
Nigba ibanuje otuwa ninu om’ayo wa
Aanu larigbaa
Ewa wo ‘se iyanu
Ota sop’otan oluwa loku ope lojasi

B’odun esi see le to
Ama tun wa laye
B’esu see gb’ogun to
Ama ri aanu gba
Loju amoko bii ki’le od’amo
Ari ire gba ao pare m’aye
Ari ire gba ao pare m’aye

B’odun esi see le to
Ama tun wa laye
B’esu see gb’ogun to
Ama ri aanu gba
Loju amoko bii ki’le od’amo
Ari ire gba ao pare m’aye
Ari ire gba ao pare m’aye.

Call: Ope ti ya o ope ti ya o
Resp: opeya
Call: ope tiya, ope tiya o
Resp: opeya
Call: ibanuje Titan ope ma Loki o
Resp: opeya
Call: oke iso di petele, opetiya o
Resp: opeya
Call: opeya opeya o opeya
Resp: opeya
Call: ijoya ijoya o ijoya
Resp: ijo ya
Call: biribiri ire Yi Kan wao
Resp: ijoya
Call: biribiri biri Ayo Yi Kan wa o
Resp: opeya
Call: odun to wolede Asanwa sire o
Resp: opeya
Call: odun eyi o asan wa sayo o

Call: ope tiya o ope tiya o
Resp: opeyaaa

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here

3 + 4 =