E kii s’Eniyan by Funke Ilori

You're not Man

669
DOWNLOAD

E KII S’ENIYAN
FUNKE ILORI [2017]
CHORUS
E kii s’eniyan o to le pa’ro
E kii s’eniyan o to le tan mi je
Awimayehun oba ti kii s’eniyan
E kii s’eniyan Olorun leje
REPEAT

Olorun kii s’eniyan ko le seke
E kii s’eniyan o
Oluwa emi gbogbo eniyan leje
E kii s’eniyan o
Ayidayida ko si ninu re
E kii s’eniyan o
Imo Re duro titi aye
E kii s’eniyan o
Iro inu Re lati irandiran ni
E kii s’eniyan o
Ologbon ninu alagbara ni ipa
Ta’lo le sagidi Si
Ohun gbogbo lati odo Re lo ti wa
E kii s’eniyan Olorun leje
[Repeat chorus]

Titobi ni igbimo alagbara ni ise
E kii s’eniyan o
O mohun gbogbo O le sohun gbogbo
E kii s’eniyan o
Kii ba idajo ati otito je
Onidajo olododo
O nwa gbogbo aya O m’ete ironu
E kii s’eniyan o
Iranlowo alainibaba Oko awon opo
Olutoju eniyan
Awosanmo ni ibora fun O
E kii s’eniyan o
Orun ati awon orun ko le gba O
E kii s’eniyan o Olorun leje
[Repeat chorus]

Lati ‘randiran ni odun Re
Igba atijo O fi ipile aye sole
Orun awon orun si ni ise Re
Won o segbe sugbon Iwo kii ti
Nitoto won o gbo bi aso
Bi ewu ni Iwo yoo paaro won
Ijoba Re wa titi aye
E kii s’eniyan o

Oro Re kii ye o [2x]
Okan na lana, loni, lola
Oro Re kii ye o
Alewilese dependable God
Oro Re kii ye o
Olorun eri, Olorun majemuni
Oro Re kii ye o
O le pe die sugbon Y’oo mu se
Oro Re kii ye o
Alewilese dependable God
Oro Re kii ye o

IPARI

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here

6 + 3 =